JUST IN: Court Sacks Ghandi As Soun Ogbomoso, Orders Fresh Selection Process
The Oyo State High Court sitting in Ogbomoso has ordered the removal of the new Soun, King Ghandi Olaoye. BBC Yoruba reported. Recall that Oyo state Government announced the selection of RCCG Pastor Ghandi Olaoye and he is installed king on the 8th of September, 2023z Saaju asiko yii ni ọmọ oye miran, ti wọn dijọ n du ipo Soun, Kabir Laoye ti pe ẹjọ pe Ghandi Olaoye ko lẹtọ lati du ipo Soun. Ile ẹjọ si pasẹ nigba naa pe ijọba ipinlẹ Oyo ko gbọdọ yan ẹnikẹni sipo naa, titi ti oun yoo fi gbe idajọ oun kalẹ. Amọ ikede jade sita pe ijọba ipinlẹ Oyo ti yan Pasitọ Ghandi Laoye bii Soun tilẹ Ogbomoso tuntun. Kí ló dé tí adájọ́ fi wọ́gilé ìyànsípò Soun tuntun? Ọmọọba Kabir Olaoye to pe ẹjọ lati tako iyansipo Ghandi salaye pe aise deede wa ninu ilana ti wọn fi yan an. O wa n rọ ile ẹjọ giga naa lati wọle iyansipo ọba tuntun yii, ko si pasẹ fun awọn afọbajẹ lati bẹrẹ igbesẹ yiyan ọmọ oye miran. Nigba to n gbe idajọ rẹ kalẹ, Adajọ Adedokun to n gbọ ẹjọ naa wa kede pe iyansipo ọba Laoye ko bofin