JUST IN: Court Sacks Ghandi As Soun Ogbomoso, Orders Fresh Selection Process
The Oyo State High Court sitting in Ogbomoso has ordered the removal of the new Soun, King Ghandi Olaoye. BBC Yoruba reported.
Recall that Oyo state Government announced the selection of RCCG Pastor Ghandi Olaoye and he is installed king on the 8th of September, 2023z
Saaju asiko yii ni α»mα» oye miran, ti wα»n dijα» n du ipo Soun, Kabir Laoye ti pe αΊΉjα» pe Ghandi Olaoye ko lαΊΉtα» lati du ipo Soun.
Ile αΊΉjα» si pasαΊΉ nigba naa pe ijα»ba ipinlαΊΉ Oyo ko gbα»dα» yan αΊΉnikαΊΉni sipo naa, titi ti oun yoo fi gbe idajα» oun kalαΊΉ.
Amα» ikede jade sita pe ijα»ba ipinlαΊΉ Oyo ti yan Pasitα» Ghandi Laoye bii Soun tilαΊΉ Ogbomoso tuntun.
KΓ lΓ³ dΓ© tΓ adΓ‘jα»́ fi wα»́gilΓ© Γ¬yΓ nsΓpΓ² Soun tuntun?
α»mα»α»ba Kabir Olaoye to pe αΊΉjα» lati tako iyansipo Ghandi salaye pe aise deede wa ninu ilana ti wα»n fi yan an.
O wa n rα» ile αΊΉjα» giga naa lati wα»le iyansipo α»ba tuntun yii, ko si pasαΊΉ fun awα»n afα»bajαΊΉ lati bαΊΉrαΊΉ igbesαΊΉ yiyan α»mα» oye miran.
Nigba to n gbe idajα» rαΊΉ kalαΊΉ, Adajα» Adedokun to n gbα» αΊΉjα» naa wa kede pe iyansipo α»ba Laoye ko bofinmu.
Bakan naa lo pasαΊΉ pe ki awα»n afα»bajαΊΉ lα» bαΊΉrαΊΉ ilana α»tun lati yan Soun tuntun
Saaju ni Adajα» Adedokun ti wα»gile αΊΉbαΊΉ mαΊΉta ti α»kan ninu awα»n olupαΊΉjα», α»mα»α»ba Adeyemi Taofiq Akorede Laoye gbe siwaju rαΊΉ.
Awα»n αΊΉbαΊΉ naa loun naa fi n pe iyansipo oriade tuntun naa nija.
A maa mu αΊΉkunrαΊΉrαΊΉ iroyin naa wa fun yin laipαΊΉ.

Comments
Post a Comment
Dear reader What's your opinion?