Posts

Showing posts from December 16, 2023

Again, Special Adviser To Gov Makinde On Education Intervention, Hon Tiamy On Assessment Visit To Schools In Akinyele Local Govt

Image
The Special Adviser to Gov Makinde On Education Intervention, Honourable Oloye Suraj Abiodun Tiamy on Friday Morning again visited some schools in Akinyele Local Government Area to have add-on assessments. Hon Tiamy who visited those schools around 9am on Friday accompanied by the Akinyele Local Government Chairmanship flagbearer of ruling People's Democratic Party (PDP) Hon Wole Akinleye, Chief of Staff to the Executive Chairman of Akinyele Local Government, Mr Ademola Adeniji and other party leaders from the same Local Government Area. The schools visited were Orogun Grammar School, HLA Primary School Ojoo, Apapa Secondary School where he identifies the challenges of the schools and spoke with the Principals and other teaching staff as well as students of the visited schools. The Governor’s aide, Hon Tiamy who documented other basic needs of those schools and promised to supply the detailed information to the Oyo state Governor, His Excellency, Engr Seyi Makinde for more improvem

*Ọ̀PỌ̀LỌ́ Ò MỌ̀NÀ ODÒ MỌ́.. AJÁ TI PADÀ SÍDÌÍ ÈÉBÌ RẸ̀ℹ️ NI ṢÈYÍ MÁKINDÉ BÁ FI ÀBÁ ÈTÒ ÌSÚNÁ ỌDÚN TÓ Ń BỌ̀ SỌ WỌ́N DEGBÉRE....! Ayélabẹ́gàn Akínkúnmi Abbas, Ọ̀kan gbóògì nínú Ẹgbẹ́ GSM Advocates

Image
   Èké dáyé, aásà dàpòmu, ìgbà yí bìrí olorì darapọ̀ mọ́ èrò ìnájà, Adégún ń d'Adéògún, Fáìlì di Fàlí,Adéẹgbẹ́ yípadà d'Adẹ̀gbẹ́, ọ̀rọ̀ àná di bámìín, Ayé yí bìrìpé, ajá padà sídìí èébì, gbogbo ẹ̀,gbògbò ẹ̀, nítorí àtijẹ....   Ẹni wagbádá sùn di dandan kó gbójú oorun wa kẹ̀kẹ́, Afàpótírọrí ò le è gbádùn oorun, ìdúró ò sí, ìbẹ̀rẹ̀ ò sí fún ẹni tó gbódó mì! Ibi a ti pé ó dàárọ̀, Yorùbá ní a kìí tún pé ẹ káalẹ́ mọ́, aláìnítìjú lè su sáàrin ọjà níta gbangba, ẹgbẹ́ tí aráabí ní ó ń ti àwọn lójú láti fọn rere rẹ̀ lọ́jọ́sí, òun ló kan asọ pọ̀ bí eégún lábala jó jàgínní yòdò wọ́nú ẹ̀ padà nítorí àti fi dandan láá wooko di Gómìnà.     Ẹni tó lójú lojú tì, àti pé orúkọ èkuru yàtọ̀ sí t'Àkàrà gédéńgbé, kárìn kápọ̀ yíyẹ ní yẹni, bí i ti ọgbà ẹ̀wọ̀n kọ́, èyí ló mú onímọ̀ ẹ̀rọ Faozey Oládọ̀tun Nurudeen ní ààrin gbùngbùn Òyó àti  Ayédẹ̀rọ̀ Ilẹ̀ Yorùbá, Shina Abíọ́lá Peller ní Àríwá Ọ̀yọ́ sọ pé ó tó gẹ́ ẹ́! Pé àwọn ò sìnà mọ́, ní wón bá tẹ̀lé ẹni tó mọ̀nà òtítọ́, Gómìnà Ṣèyí Mákindé wọnú ẹ